Ìròyìn yàjó-yàjó. Ìyàwó Ọṣìbọ́nà, ọkùnrin tó nilé alájà mọ́kànlélógún tó dà wó ní Ìkòyí l'Eko ti ń jà sáwọn dúkìá ọkùnrin náà pẹ̀lú àwọn mọ̀lẹ́bí olóògbé. Ọkọ̀, owó báńkì, àti àwọn dúkìá olówó iyebíye míràn niwọ́n ń jà sí, Lọ̀rọ̀ bá dọ̀rọ̀ agbẹjọ́rò. Àwọn ìbátan arákùnrin Ọṣì...
Share this page with your family and friends.