To continue using the site you need to read the revised version and agree to the policies
  Thanks for your feedback. Your report has been submitted.
Kòpẹ́-kòpẹ̀ yí ni ìròyìn òhun gbàgboro kan wípé àgbà òṣèré orí ìtàgé àti sinimá àgbéléwò ni Babatunde Omidina tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ mọ̀ sí "Baba Suwe" ti jáde láyé lónìí ọjọ́ Ajé ọjọ́ kejilelogun oṣù kọkànlá. Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ìròyìn ti sọọ tẹ́lẹ̀ pé ara arákùnrin náà ko yá. Àmọ́ àìsàn k...
