To continue using the site you need to read the revised version and agree to the policies
Thanks for your feedback. Your report has been submitted.
Ilé ẹjọ́ Májísíréeti kan tó fìkalẹ̀ ságbègbè Ìkẹ̀jà ti gba onídùúró arákùnrin òṣìṣẹ́ báńkì ẹni ọdún mọ́kànlélọ́gbọ̀n kan, Ridwan Adejoju lówó miliọọnu kan Náírà látàrí ẹ̀sùn ìwà jìbìtì tí wọ́n fi kàn án. Arákùnrin ọ̀hún ni wón sọ wípé ó jí owó tótó ẹgbẹ̀rún lọ́nà ẹgbẹ̀ta pẹ̀lú ọg...
