Blogs Home » Browse Blogs » Ọ̀RỌ̀ ÒṢÈLÚ ÌPÍNLẸ̀ ÈKÌTÌ

Ọ̀RỌ̀ ÒṢÈLÚ ÌPÍNLẸ̀ ÈKÌTÌ

power quadrant system  Látàrí ìbáṣepọ̀ tó dánmọ́nrá àti ìfọwọ́ Ìfẹ́ múra ẹni tó ń lọ lọ́wọ́ láàárín gómìnà tẹ́lẹ̀ rí ní Ìpínlẹ̀ Èkìtì Ayodele Fayoṣe àti gomina lọ́wọ́-lọ́wọ́ Dr. Káyọ̀dé Fayẹmi tí Wọ́n jọjẹ́ àgbà ọ̀jẹ̀ lágbo òṣèlú ti ń jẹ́ kí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ó máa sọ oríṣiríṣi  àmọ́ èyí kò dí olúkúlùkù wọn lọ́wọ́ láti ṣe àtìlẹ́yìn fún ẹnikẹ́ni tí ó bá fẹ́ẹ́ dupò gómìnà nínú ẹgbẹ́ òṣèlú tí ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn ń ṣe. Àmọ́ ohun tí ó ń jẹ́ ìkọminú fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn lásìkò yí pàápàá àwọn olùdìbò nipé  kí ló le fàá tó fi jẹ́ pé lásìkò tí ẹgbẹ́ òṣèlú gbogbo ń wá ọ̀nà láti rí i wípé àwọn làwọ́n wà nílé ìjọba ni Òkè Ayoba lọ́dún 2022 ni ìbáṣepọ̀ wá ń wà láàárín Káyọ̀dé Fáyẹmí àti Ayodele Fayoṣe tí ó sì jé pé ẹgbẹ́ òṣèlú ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ni wọn jọ wà. Èyí ni kò   láàárín àwọn olóṣèlú akẹgbẹ́ wọn. Àmọ́ o  àwọn kọ̀ọ̀kan ní Ìpínlẹ̀ Èkìtì ń fojúunú wo ohun kan tí ó ti ṣẹlẹ̀ rí nígbà tí àtúndì ìbò fẹ́ẹ́ wáyé lọ́dún 2009 ní Ìpínlẹ̀ Èkìtì nígbà náà lóhùn tí Ayodele Fayoṣe tí ó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ òṣèlú PDP ń s'àtìlẹyìn fún Kayode Fáyẹmí tí ó jẹ́ òǹdíje-dupò gómìnà n 

Photos

0 albums found