-
1.6K Views
0 Comments
2 Likes
0 Reviews
Kòpẹ́-kòpẹ̀ yí ni ìròyìn òhun gbàgboro kan wípé àgbà òṣèré orí ìtàgé àti sinimá àgbéléwò ni Babatunde Omidina tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ mọ̀ sí "Baba Suwe" ti jáde láyé lónìí ọjọ́ Ajé ọjọ́ kejilelogun oṣù kọkànlá.
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ìròyìn ti sọọ tẹ́lẹ̀ pé ara arákùnrin náà ko yá. Àmọ́ àìsàn kúkú la rí wò, a ò rí tọlọ́jọ́ ṣe.
Kí Olódùmarè ó ṣekú nisinmi fún un.
Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ìròyìn nípa rẹ ń bọ̀ láìpẹ́.
Baba Suwe!
Sun un ree o.