Ede Yoruba dun ,Awon itumo oro lede oyinbo ti o ti rapala wonu ede Yoruba .
But - Ṣugbọn/Amọ
Except - Ayafi
However - Ẹwẹ
Therefore - Wayii
Nevertheless - Sibẹsibẹ
Whatever - Ohunkohun
Precisely - Gangan
Exactly - Ni pato
Very much - Gidi gaan
Unless - Afi
Without - Laisi/Laini
Likewise/Moreover - Bakanaa
Although/Though - Botilẹjẹpe
Especially - Agaga
Then - Lẹyinaa
Eventually - Ọrẹyin
O 'right' - O tọna
O 'wrong' - Ko tọ/Ko tọna
Because (of) - Ni'tori (pé)
Mo 'Like' - Mo fẹran, Mo nifẹ
Even - Paapaa
Most especially - Paapaa julọ
In addition (to)- Ni afikun
Worry - Iyọnu
In summary - Ni ṣoki
Ma 'worry' - Ma ṣe'yọnu
Sincerely - Ni Tọkan / Tọkantọkan
Truly - Ni Tootọ / Ni ododo
So - (Ni) tori naa
Ṣe 'mistake' - Ṣe aṣiṣe
A must/Compulsory - Pọn/Kan dandan
Mo 'pass/succeed' - Mo yege
Mo 'fail' - Mo kùnà
Ma 'rush' - Ma kanju
Of - ti, E.g Alaafin 'of' Oyo - Alaafin Oyo/ ti Oyo
How come? - Bawo loṣejẹ/Eeṣe
Need - Nílò
Let alone - Ambeletase/Ambọsibọsi
Force/By force - Ipá/T'ipá
Help - Iranlọwọ/Ìrànwọ
Anybody - Ẹnikankan
O 'pay' - O san
Whoever - Ẹnikẹni
Mo 'appreciate' - Mo mọ rírì
Anyone - Ẹnikankan
Anything - Nkankan/Eyikeyi
Anyhow -Lọnakọna
Shop - Isọ itaja
Mo 'try/attempt' - Mo Gbiyanju
No matter - Botiwu/Botilewu
Separately - Lọtọọtọ
O 'different' - O yatọ
For real? - Ṣe Lotitọ/Lootọ?
Anyway - Lọnakan ná
Any day - L'ọjọkọjọ
Whichever - Eyikeyi/Eyiowu
Since - Niwọn igba
Normally - Ni dede
Colour - Awọ
Or - Abi
Still - Sibẹ
Aside/apart from - Yatọ si
Ko 'Easy/Simple' - Ko rọrun
Actually - Lootọ/Ni tootọ
Better - San ju, Dara ju
O wa 'important' - O ṣe pataki
Easily - Irọrun
O 'better' - O suwọn
Disappointment - Ijakulẹ
O 'bad' - O buru
Understand - Ni òye
Advice - Imọran
Really - Gaan
O wa 'okay' - O dara bẹẹ
Very - Gidi/Gidigan
Ko 'serious' (person) - Alawada/Oniyẹyẹ ni
Last time - Igbakẹyin
Consequence - Atunbọtan
Outcome - Abajade
Reply - Esi
Last year/season - Eṣi
At once/Immediately - Lẹsẹkẹsẹ
Instantly - Lọgan
Mo 'send' - Mo (fi) ranṣe
Until - Titi di/da
Wa ni 'standby' - Wa ni digbi
O 'fine' - O dara/rẹwà/lẹwa
Yoruba dun,ede Yoruba larinrin