I concur!
I agree with you that: HE's the KING of kings
Oba to da iku ti kii ku
Oba to oorun ti kii sun
Oba to da onje t'ebi kii pa
Oba to da Omi ti ongbe kii gbe
Eti ninla ti ngb'ejo gbogbo adarihunrun
Oba ti kii pa'ro
Oba ti kii paa'ro
Oba ti kii ti
Oba ti kii te
Oba ti kii kabuku
Oba to kii pa'poo da
Kabiyesi Oba gbogbo re ninu gbogbo re ...
Good beautiful morning to Blessed you. Do have a Fruitful Tuesday.
Ko-ni-baje o!
Share this page with your family and friends.