To continue using the site you need to read the revised version and agree to the policies
Thanks for your feedback. Your report has been submitted.
Ọwọ́ titẹ ògbólógbò ọkùnrin ajínigbé kan tóti ń dàwọn èèyàn láàmú ni Ìpínlẹ̀ Èkìtì àtì Òndó. Arákùnrin ògbólógbòó ajínigbé kan tórúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Bùnmi Ògúnrẹ̀mí ẹni ọdún mọ́kàdínláàdọ́ta lọ́wọ́ àwọn Ọlọpa titẹ báyìí ni ìpínlè Ekiti. Arákùnrin yí nìròyìn fìdí rẹ múlè wípé ó fẹnu ...
