Kaabiesi Aláyélúwà Ọba Làmídì Adéyẹmí III ti fa àwọn akẹ́kọ̀ọ́ méjì tí àwọn ajínigbé jígbé ní agbègbè Àgbàdo crossing ni Ìpínlẹ̀ Ògùn lé àwọn òbí wọn lọ́wọ́. Nígbà tí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ilé ẹ̀kọ́ gíga girama náà ń ṣàlàyé bí wọn ṣe báraawọn n'ilu Ọ̀yọ́ àti ohun tí ojú wọn rí lọ́wọ́ à...
Share this page with your family and friends.