Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ti dá olùkọ́ mẹta dúró bayi látàrí ẹ̀sùn ìbánilòpọ̀ lọ́nà àìtọ́ tí wọ́n fi kàn wọn nílé ẹ̀kọ́ Basic School, to wà n'ilu Ògbómọ̀ṣọ́, nipinle Ọ̀yọ́. Àtẹ̀jáde yí wáyé latenu ẹni tí ó jẹ́ kọmíṣọ́nà fún ètò ẹ̀kọ́, ìmọ̀ Sayennsi àti ìmọ̀ ìgbàlódé, Arákùnrin Rahman ...
Afrosky, a vibrant social media platform dedicated to connecting people of African descent worldwide. We provide a space for users to share their experiences, connect with like-minded individuals, and celebrate African culture and heritage.
We strive to foster a supportive and inclusive community where users feel empowered to express themselves authentically.
Share this page with your family and friends.