Agbẹjọ́rò àgbà nílẹ̀yí tótúnjẹ́ mínísítà ìdájọ́, Arákùnrin Abubakar Malami ti sẹ́ ẹ̀sùn kan tí wọ́n fi kàn án wípé ó lẹ́bọ lẹ́rù nípa àwọn ohun ìní tí ìjọba àpapò gbà lọ́wọ́ àwọn ènìyàn tí wọn ń tà lọ́nà àìtọ́. Nínú àtẹ̀jáde ọ̀rọ̀ tí ẹni tójẹ̀ alukoro fún ọ̀rọ̀ ìròyìn rẹ̀ Dr. Um...
Share this page with your family and friends.