Popular Tags

Anything in here will be replaced on browsers that support the canvas element

See All Tags »
1 Blog found.
  • December 2 2019

    Bí ó ti lẹ̀ jẹ́ pé ìròyìn nípa ikú òjijì tó pa akẹ́kọ̀ọ́ ilé ẹ̀kọ́ Dowen Sylvester Oromoni kì í ṣe tuntun mọ, àmọ́ ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ènìyàn pàápàá àwọn abiamọ rere tòótọ́ ni ó wùn láti rídìí òkodoro ohun tó fa sábàbí ikú rẹ. Lọ́sẹ̀ tó kọjá ni ìròyìn nípa ikú ọmọdékùnrin náà tànká w...