Ìwà ọmọlúwàbí jẹ́ ìwà kan pàtàkì tí ènìyàn gbọ́dọ̀ ní lọ́wọ́, nítorí lọ́pọ̀lọpọ̀ ìgbà ó máa ń sábà á ṣílẹ̀kùn oore àti ìrànwọ́ àìlérò fúnni. Àtipé ó dàbí òògùn ẹ̀yọ́nú nítorí pé, ọ̀pọ̀ ènìyàn ni ó máa ń fẹ́ bá ọmọlúwàbí ènìyàn ṣe. Irúfẹ́ ìwà ọmọlúwàbí yi ni arábìnrin oníṣòwò kárà...
Share this page with your family and friends.