Ọwọ panpẹ ajọ oloogun oloro orileede Naijiria NDLEA tun ti tẹ ogbologbo oloogun oloro kan ni ilu Eko, Ni adugbo Victoria Garden City, Lekki ni ilu Eko ni alukoro ajọ NDLEA, Femi Babafemi sọ pe awọn ti ri oogun oloro Tramadol gba. Babafemi ni iye owo oogun oloro naa le ni biliọn...
Share this page with your family and friends.