Ọmọ ọdẹ kanni ilu Dutse Gogo nitosi Kaiama nipinlẹ Kwara ti yinbọn pa aburo rẹ lasiko ti wọn n dan ogun ayẹta ti baba wọn ṣẹṣẹ ṣe wo. Ọmọ ọdẹ naa ti orukọ rẹ n jẹ Abubakar Abubakar pẹlu baba rẹ ati aburo rẹ ti orukọ rẹ n jẹ Yusuf Abubakar gbiyanju lati dan ogun ayẹta naa wo lọjọ ...
Share this page with your family and friends.