To continue using the site you need to read the revised version and agree to the policies
  Thanks for your feedback. Your report has been submitted.
Ohun ìjọlójú gbáà ló jẹ́ fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn nígbà tí arákùnrin kàn Festus James ń kà bòrò-bòrò níwájú àwọn agbófinró àti àwọn oníròyìn láìpẹ́ yí ni ìpínlẹ̀ Ondo. Arákùnrin ẹni ọdún mẹ́rìndínlọ́gọ́ta (56) ohun tí ọ̀pọ̀ èèyàn mọ̀ gẹ́gẹ́ bí òjíṣẹ́ Ọlọ́run ni ó hùwà kàyééfì kan n...
